islamkingdomfacebook


IRUN IGBATI OORUN ATI OSUPA BA WỌỌKUN

IRUN IGBATI OORUN ATI OSUPA BA WỌỌKUN

3333
Eko ni soki
Oorun ati osupa je aami meji ninu awon aamin Olohun oba ti ola re ga, Olohun maa nte awon mejeeji ri nigbati o ba ri ese ati iyapa ase re lodo awon eru re, ki awon eru lee seri pada si odo re ati ki won le ronupiwada kuro nibi awon ese won. Nitidajudaju, Olohun oba alekeola ti se irun iteri oorun tabi osupa lofin fun iruu isele yi, awon eru yio ke gbajare losi odo Olohun, won yio si wa iranlowo re, beeni Olohun yio ba re adanwo yi kuro fun won. ء.

 

 

Awọn erongba lori Khutuba naa:

 

1-     Sise alaye titobi Ọlọhun, atipe o pa dandan ati maa tẹ le E, ki a si ma sẹ Ẹ;

2-     Ise alaye pe Ọlọhun A maa jowu lori awọn ẹsẹ;

3-     Sise alaye awọn idajọ irun Kusufu;

4-     Sise alaye nkan ti o yẹ ki awọn eniyan maa se lasiko Khusufu.

الحمد لله ربّ العالَمين، والصّلاة والسّلام على نبيّنا محمّد وعلى آله وصحبه وسلّم، وبعد؛ فإنّ اختلاف الليل والنهار وتكويرهما من آيات الله لينتفع الإنسان، وجعلهما تحت تسخيره. و بقوله: {وسخر لكم الشمس والقمر دائبين وسخر لكم الليل النهار} [إبراهيم 14: 22].

Yiyatọ ọsan ati oru, ati bi Ọlọhun ti da wọn, jẹ ami nla ninu awọn ami Ọlọhun; ki awọn eniyan le se anfaani lara rẹ. Ọlọhun sọ wipe:

قال الله تعالى: (ومن آياته الليل والنهار والشمس والقمر لا تسجد وا للشمس ولا للقمر واسجدوا لله الذي خلقهن إن كنتم إياه تعبدون)، [فصلت 41: 37].

(Ninu awọn ami Ọlọhun ni oru, ọsan, oorun ati osupa, ẹ ma se fi eri kanlẹ fun oorun bẹẹ ẹyin ko gbọdọ fi eri balẹ fun osupa, sugbọn ki ẹ fi ori balẹ fun Ọlọhun ti O da wọn, ti o ba sewipe Oun (Ọlọhun) ni ẹyin n sin lododo) [Fussilat: 41: 37].

Tun wo suratul Ibrahim 14: 32-34.

(وسخر لكم الفلك لتجري في البحر بأمره وسخر لكم الأنهار . وآتاكم من كل ما سألتموه وإن تعدوا نعمة الله لا تحصوها إن الإنسان لظلوم كفار) [إبراهيم 14: 32-34].

Kosi ẹniti o le yi eto lilọ bibọ oorun ati osupa pada ayafi Ọlọhun nikan soso. Orisirisi awọn okunfa ti adamọ ni o wa ti mumini ati keferi ni igbagbọ si wọn. Bakanaa ni awọn okunfa ti sẹri'ah naa wa, ti mumini ni igbagbọ si wọn, sugbọn ti keferi saigbagbọ si. Ọlọhun sọwipe: (bẹẹ ni oorun n rin lọsi aaye rẹ, dajudaju eleyi jẹ eto Ọba Alagbara Onimimọ). Wo suratu Yaasin 36: 38-40.

(والشمس تجري لمستقر لها ذلك تقدير العزيز العليم) [يس 36: 38]. وقوله: (لا الشمس ينبغي لها أن تدرك القمر ولا الليل سابق النهار وكل في فلك يسبحون) [يس 36: 40]. وعن أبي موسى قال خسفت الشمس في زمن النبي فقام فزعا يخشى أن تكون الساعة حتى أتى المسجد فقام يصلي بأطول قيام وركوع وسجود ما رأيته يفعله في صلاة قط ثم قال إن هذه الآيات التي يرسل الله لا تكون لموت أحد ولا لحياته، ولكن الله يرسلها يخوف بها عباده، فإذا رأيتم منها شيئا فافزعوا إلى ذكره ودعائه واستغفاره"- أخرجه مسلم.

Sisẹlẹ Khusuf jẹ ikilọ lati ọdọ Ọlọhun latari jijinna ti awọn eniyan jinna si ofin Ọlọhun. Ọlọhun sọwipe:

(ولو يؤاخذ الله الناس بما كسبوا ما ترك على ظهرها من دابة ولكن يؤخرهم إلى أجل مسمى فإذا جاء أجلهم فإن الله كان بعباده بصيرا) [فاطر 35: 45].

(Ti Ọlọhun ba fẹ mu awọn eniyan pẹlu isẹ ọwọ wọn ni, ko ba ti sẹku ẹnikan lori ilẹ, sugbọn O nlọwọn lara di asiko kan ti O sọ, ti asiko wọn naa basi de, dajudaju Ọlọhun jẹ Oluriran ri awọn ẹru Rẹ). [Faatir 35: 45].

وعن جابر بن عبد الله قال كسفت الشمس على عهد رسول الله في يوم شديد الحر فصلى رسول الله بأصحابه، فأطال القيام حتى جعلوا يخرون ثم ركع فأطال ثم رفع فأطال ثم ركع فأطال ثم رفع فأطال ثم سجد سجدتين ثم قام فصنع نحوا من ذاك فكانت أربع ركعات وأربع سجدات، ثم قال إنه عرض علي كل شيء تولجونه، فعرضت علي الجنة حتى لو تناولت منها قطفا أخذته أو قال تناولت منها قطفا فقصرت يدي عنه وعرضت علي النار فرأيت فيها امرأة من بني إسرائيل تعذب في هرة لها ربطتها فلم تطعمها ولم تدعها تأكل من خشاش الأرض ورأيت أبا ثمامة عمرو بن مالك يجر قصبه في النار وإنهم كانوا يقولون إن الشمس والقمر لا يخسفان إلا لموت عظيم وإنهما آيتان من آيات الله يريكموهما فإذا خسفا فصلوا حتى تنجلي"- أخرجه مسلم.

Sise afirinlẹ iya inu saare, ati sise ikilọ rẹ fun awọn eniyan paapajulọ iya ina. Ojisẹ Ọlọhun se ikilọ iya saare ati iya ina fun wa ninu ọpọlọpọ Hadiisi.

يا أمة محمد والله ما من أحد أغير من الله أن يزني عبده ، أو تزني أمته ، يا أمة محمد لو تعلمون ما أعلم لضحكتم قليلا ، ولبكيتم كثيرا ، وايم الله - يعني والله - لقد رأيت منذ قمت أصلي ما أنتم لاقوه من أمر دنياكم وآخرتكم ، ما من شيء لم أكن رأيته، إلا رأيته في مقامي هذا حتى الجنة والنار رأيت النار يحطم بعضها بعضا، فلم أر كاليوم منظرا قط أفظع، ورأيت فيها عمرو بن لحي الخزاعي يجر قصبه - يعني أمعاءه - ورأيت فيها امراة تعذب في هرة لها ربطتها ، فلم تطعمها، ولم تدعها تأكل من خشاش الأرض، ولقد رأيتكم تفتنون في قبوركم ، كفتنة الدجال يؤتى أحدكم ، فيقال : ما علمك بهذا الرجل ؟ فأما المؤمن أو الموقن، فيقول: محمد رسول الله جاءنا بالبينات والهدى، فأجبنا، وآمنا واتبعنا، فيقال: نم صالحا ، فقد علمنا إن كنت لموقنا. وأما المنافق أو المرتاب ، فيقول : لا أدري سمعت الناس يقولون شيئا، فقلته".

 

 

الحمد لله، والصّلاة والسّلام على رسول الله، وبعد؛ فإضافة إلى الأدلة السابقة يمكن أن يستدل بحديث حذيفة قال: كان رسول الله إذا حزبه أمر صلى"- أخرجه ابن جرير. وقال علقمة: "إذا فزعتم من أفق من آفاق السماء فافزعوا إلى الصلاة"- أخرجه ابن أبي شيبة.

Sise irun kiki ni ofin lasiko khusufu, nitoripe Ojisẹ Ọlọhun (صلّى الله عليه وسلّم) amaa kirun nigbati nkankan ba sẹlẹ.

Alaye bi a tise n kiriun Khusuf a ri ninu Hadiisi Iya nla wa 'Aishat (رضي الله عنها) tosọpe: oorun wọọkun laye Annabi (صلّى الله عليه وسلّم), o si ki irun pẹlu awọn eniyan, o naro ti osi pẹ lori inaro naa, lẹyin naa o rukuu (o tẹriba) osi pẹ lori ruku'u naa. lẹyin naa o naro ti o si pẹ lori inaro naa, sugbọn koto ti inaro alakọkọ. lẹyin naa o rukuu (o tẹriba) osi pẹ lori ruku'u naa, sugbọn koto ti ruku'u alakọkọ naa. lẹyin naa o forikanlẹ ti o si pẹ lori iforikanlẹ naa. O si ki rak'at ẹlẹẹkeji gẹgẹ bi o ti ki ti alakọkọ, lẹyin naa ni o pẹyinda, ti oorun si ti han, o siba awọn eniyan sọrọ (khutubah), o se ọpẹ fun Ọlọhun osi se ẹyin fun Un, ti o si wipe: dajudaju oorun ati osupa jẹ ami meji ninu awọn ami Ọlọhun, wọn kii wọọkun nitori iku ẹda kan tabi nitori isẹmii rẹ, ti ẹ ba ri ti oorun tabi osupa ba wọọkun ki ẹ se adua, ki ẹ gbe Ọlọhun tobi, ki ẹ kirun, ki ẹ si se saara…".

Sisẹri pada si ọdọ Ọlọhun, ati fifi ẹsẹ silẹ pẹlu sise dọgba laarin awọn eniyan. Ọlọhun sọpe:

{يا أيها الذين آمنوا توبوا إلى الله توبة نصوحا عسى ربكم أن يكفر عنكم سيئاتكم ويدخلكم جنات تجري من تحتها الأنهار يوم لا يخزي الله النبي والذين آمنوا معه نورهم يسعى بين أيديهم وبأيمانهم يقولون ربنا أتمم لنا نورنا واغفر لنا إنك على كل شيء قدير} [التّحريم 66: 8].

(Mo pe ẹyin ti ẹ gbagbọ lododo, ẹ tuba ni tutuba ti o mọ kanga, ki Ọlọhun lee pa awọn asise yin rẹ, ti yoo si muyin wọ awọn alijannah ti awọn odo n san lọ labẹwọn, ni ọjọ ti Ọlọhun ko ni doju ti Annab ati awọn ti wọn gbagbọ lododo pẹlu rẹ, imọlẹ n tan niwaju wọn ati lọwọ ọtun wọn. wọn yoo si maa sọpe: Oluwa wa! Pe imọlẹ wa funwa, si fi ori ẹsẹ wa jinwa, dajudaju Alagbara lori gbogbo nkan ni Irẹ) [At-Tahrim 66: 8].

Tun wo:

{أفلم يروا إلى ما بين أيديهم وما خلفهم من السماء والأرض إن نشأ نخسف بهم الأرض أو نسقط عليهم كسفا من السماء إن في ذلك لآية لكل عبد منيب} [السّبأ 34: 9].

Ki Ọlọhun se amọna wa, ki O se aforijin awọn ẹsẹ wa (aamin).