islamkingdomfacebook


Ọna ipepe awọn Annabi si oju ọna Ọlọhun

Ọna ipepe awọn Annabi  si oju ọna Ọlọhun

17160
Eko ni soki
Dajudaju, ninu awon abala ti o han julo ninu itan awon anabi ati ojise ni abala ipepe si ojuona Olohun Oba ti ola re ga ti o gbongbon, ipepe yi ni ilana tire eleyiti o foju han, ti ko si iruju nibe, ninu re ni; ini imo nipa ohun ti a npepe sibe, ati isise too ohun ti a npepe sibe, ati ibere ipepe lati ibiti o pataki julo siwaju imiran ati igba iroyin pelu iwa rere ati ogbon nibi ise ipepe.

1-     Riran awọn eniyan leti igbiyanju awọn Annabi Ọlọhun lori pipepe lọ si oju ọna Ọlọhun;

2-     Gbigba awọn olupepe si oju ọna Ọlọhun niyanju ki wọn maa tẹ le oju ọna awọn Annabi Ọlọhun nibi ipepe wọn;

3-     Sise igbiyanju ati se amulo ọna miran fun ipepe nigbati bukata ba wa fun un.

الحمد لله ربّ العالَمين. والصّلاة والسّلام على أفضل رسل الله. وبعد؛ إنّ رسل الله أقوام مصطفون أخيار للدعوة. أرسلهم الله مبشّرين ومنذرين. قال تعالى: {لكل منكم جعلنا شرعةً ومنهاجاً} [المائدة 5 :48]. وقال: {شَرَعَ لكم من الدِّين ما وصَّى به نوحاً والذي أوحينا إليك وما وصّينا به إبراهيم وموسى وعيسى أن أقيموا الدّين ولا تتفرّقوا فيه} [الشّورى 42: 13].

Awọn Ojisẹ Ọlọhun ni awọn ẹni ẹsa fun ipepe si oju ọna Ọlọhun. Ọlọhun sọ ninu Al-kuran wipe:

(قالوا يا صالح قد كنت فينا مرجوا قبل هذا أتنهانا أن نعبد ما يعبد آباؤنا وإننا لفي شك مما تدعونا إليه مريب) [هود 11: 62].

(wọn wipe: irẹ Salih! iwọ tiwa laarin wa ni ẹni ti a n rankan siwaju eyi, se iwọ yoo kọ funwa lati sin awọn nkan ti awọn babaa wa n sin bi? Dajudaju awa wa ni inu iyemeji si nkan ti o n pe wa si) [Hud 11: 62].

Tun wo suratul Saad 38: 45-49.

وقوله: {واذكر عبادنا إبراهيم وإسحاق ويعقوب أولي الأيدي والأبصار. إنا أخلصناهم بخالصة ذكرى الدار وإنهم عندنا لمن المصطفين الأخيار. واذكر إسماعيل واليسع وذا الكفل وكل من الأخيار} [ص 38: 45-49].

Iwoye si gbogbo awọn ọrọ, ki a si to wọn nibamu si bi wọn ba se se pataki si. 'Abdulahi ibn 'Abbas (رضي الله عنه) gba ẹgbawa wipe ni igbati Annabi (صلّى الله عليه وسلّم) ran Mu'aasu bun Jabal (رضي الله عنه) lọsi ilu Yamen o wi fun un pe: "dajudaju iwọ n lọ si ọdọ ijọ kan ti a fun ni tira, ti iwọ ba de ọdọ wọn, nkan akọkọ ti iwọ yoo pewọn si ni ijẹri wipe ko si Oluwa kan ti o lẹtọ lati jọsin fun lododo afi Ọlọhun nikan soso, atipe Annabi ojisẹ Rẹ ni, ti wọn ba tẹ le ọ bẹẹ,  fun wọn ni iro wipe Ọlọhun se irun marun un lọranyan lewọn lori ni gbogbo ojoojumọ. Ti wọn ba tun tẹ leọ bẹẹ, wa fun wọn ni iro wipe Ọlọhun se Sakah ni ọranyan ninu owo awọn olowo wọn fun awọn alaini wọn. Ti wọn ba si tun tẹ le ọ bẹẹ, nigba naa ki o sọra fun awọn ojulowo owo wọn, ki o si sọra fun epe ẹniti wọn se abosi fun, nitoripe ko si gaga kankan laarin adua rẹ ati Ọlọhun. [Bukhari].

Awọn ibujoko, aaye, asiko ti o baamu. Sise amojuto awọn onipo lawujọ ati awọn ti ko ni agbara, awọn yii  gaan ni opo ipepe. Ọlọhun sọ wipe:

{وما أرسلنا من رسول إلا بلسان قومه ليبين لهم فيضل الله من يشاء ويهدي من يشاء وهو العزيز الحكيم"} [إبراهيم 14: 4].

(A ko ran ojisẹ kan nisẹ ayafi pẹlu ahọn awọn ijọ rẹ, ki o le baa se alaye fun wọn, ti Ọlọhun yoo si jẹ ki ẹni tobafẹ sọnu fun rarẹ ko sọnu, ti yoo si fi ẹniti O ba fẹ mọna. Oun ni Alagbara Ọjọgbọn) [Ibrahim 14: 4].

Tito nkan lẹsẹlẹsẹ, ati sise akolekan adisọkan nipilẹ. Wo ọrọ Annabi Nuhu ati awọn ijọ rẹ:

{وما أنا بطارد المؤمنين. إن أنا إلا نذير مبين. قالوا لئن لم تنته يا نوح لتكونن من المرجومين. قال رب إن قومي كذبون. فافتح بيني وبينهم فتحا ونجني ومن معي من المؤمنين} [الشعراء 26: 114-118].

(emi ko lee le awọn olugbagbọ ododo. emi ko jẹ nkankan tayọ olusekilọ ti o yanju. Wọn wipe: irẹ Nuhu! Bi o ko ba dẹkun ipe rẹ, iwọ yoo wa ni inu awọn ẹniti a o ju loko. O sọ pe: Oluwa mi! Awọn ijọ mi mati pemi ni opurọ!. Nitorinaa se isipaya laarin emi pẹlu wọn ni isipaya, ki O si lami ati awọn olugbagbọ ododo ti wọn wa pẹlu mi ninu wọn) [Al-Shu'arau 26: 114-118].

Awọn irinsẹ ati ọna agbekalẹ. Diduro sinsin lori ododo, ifọwọsowọpọ pẹlu awọn ọmọ- iya ẹsin, imaa sọrọ pẹlẹ, imaa lo ẹri ti o fẹsẹrinlẹ, imaa gba ẹniti a n pe laye yiyiiri ọrọ wo, imaa se suru. Wo suratut-Tọhah 20: 29-35, Hudu 11: 62, Israa 17: 73-75.

{واجعل لي وزيرا من أهلي. هارون أخي. اشدد به أزري. وأشركه في أمري. كي نسبحك كثيرا. ونذكرك كثيرا. إنك كنت بنا بصيرا} [طه 20: 29-35]. وانظر إلى صالح وقومه في قوله تعالى: {قالوا يا صالح قد كنت فينا مرجوا قبل هذا أتنهانا أن نعبد ما يعبد آباؤنا وإننا لفي شك مما تدعونا إليه مريب} [هود 11: 62]، وانظر إلى محمد: {وإن كادوا ليفتنونك عن الذي أوحينا إليك لتفتري علينا غيره وإذا لاتخذوك خليلا. ولولا أن ثبتناك لقد كدت تركن إليهم شيئا قليلا. إذا لأذقناك ضعف الحياة وضعف الممات ثم لا تجد لك علينا نصيرا } [الإسراء 17: 73-75].

الحمد لله ربّ العالَمين، والصّلاة والسّلام على رسول الله، وبعد؛ عباد الله انظروا في حوار نبِيّ الله إبراهيم وموسى عليهما الصّلاة والسّلام الذين حكاهما لنا القرآن الكريم: {وإذ قال إبراهيم لأبيه آزر أتتخذ أصناما آلهة إني أراك وقومك في ضلال مبين. وكذلك نري إبراهيم ملكوت السماوات والأرض وليكون من الموقنين.فلما جن عليه الليل رأى كوكبا قال هذا ربي فلما أفل قال لا أحب الآفلين. فلما رأى القمر بازغا قال هذا ربي فلما أفل قال لئن لم يهدني ربي لأكونن من القوم الضالين. فلما رأى الشمس بازغة قال هذا ربي هذا أكبر فلما أفلت قال يا قوم إني بريء مما تشركون.إني وجهت وجهي للذي فطر السماوات والأرض حنيفا وما أنا من المشركين. وحاجه قومه قال أتحاجوني في الله وقد هدان ولا أخاف ما تشركون به إلا أن يشاء ربي شيئا وسع ربي كل شيء علما أفلا تتذكرون. وكيف أخاف ما أشركتم ولا تخافون أنكم أشركتم بالله ما لم ينزل به عليكم سلطانا فأي الفريقين أحق بالأمن إن كنتم تعلمون. الذين آمنوا ولم يلبسوا إيمانهم بظلم أولئك لهم الأمن وهم مهتدون. وتلك حجتنا آتيناها إبراهيم على قومه نرفع درجات من نشاء إن ربك حكيم عليم} [الأنعام 6: 74-83]. ويوجد المثال أيضا في قصة موسى وفرعون، قال تعالى: {فأتياه فقولا إنا رسولا ربك فأرسل معنا بني إسرائيل ولا تعذبهم قد جئناك بآية من ربك والسلام على من اتبع الهدى. إنا قد أوحي إلينا أن العذاب على من كذب وتولى، قال فمن ربكما يا موسى. قال ربنا الذي أعطى كل شيء خلقه ثم هدى. قال فما بال القرون الأولى، قال علمها عند ربي في كتاب لا يضل ربي ولا ينسى، الذي جعل لكم الأرض مهدا وسلك لكم فيها سبلا وأنزل من السماء ماء فأخرجنا به أزواجا من نبات شتى. كلوا وارعوا أنعامكم إن في ذلك لآيات لأولي النهى. منها خلقناكم وفيها نعيدكم ومنها نخرجكم تارة أخرى. ولقد أريناه آياتنا كلها فكذب وأبى}. [طه 20: 47-56].

Imaa mu ẹri ti o jẹti adamọ (eyiti a n fi oju ri) wa, ati lati inu Al-kuran, ati eyi ti o ba laakaye mu wa. Ninu awọn aayat ti a ti darukọ soke, wo awọn ẹri Annabi Ibrahim ninu suratul Al-An'am 6: 74-83. Tun wo itan Annabi Musa ati Fir'aona ninu suratul Tọha 20: 47-56.

Ọgbọn, waasi ti o dara, awọn itan, iseni ni ojukokoro ati idẹrubani jẹ ara awọn ọna ipepe awọn Annabi Ọlọhun. Wo suratun-Nahal 16: 125.

(ولا تجادلوا أهل الكتاب إلا بالتي هي أحسن إلا الذين ظلموا منهم) [النّحل 16: 125].

Imaa gbe awọn iransẹ ati asoju dide lati lọọ pepe si oju ọna Ọlọhun, gẹgẹ bi Annabi (صلّى الله عليه وسلّم) se ran ijọ ti Malik ibn Al-Huwairith (رضي الله عنه) jẹ ọkan larawọn ki wọn maa lọ kọ awọn eniyan wọn lẹsin ki wọn maa kirun. [Bukhari]. Bakanaa ni Annabi ran Abu 'Ubaidah ibn Jarah (رضي الله عنه) lọ si Najran ki o lọ kọ wọn lẹsin. [Bukhari].

Sise amulo awokọse ati ayọka jẹ ọna tuntun ti o wulo.

وقد قيل: (الحكمة ضالة المؤمن أنى وجدها فهو أحق بها). روى مرسلا من حديث زيد بن أسلم رفعه إلى النبي.  أخرجه الترمذي.

وصلّى الله وسلّم وبارك وأنعم على نبيّنا محمّد وعلى آله وصحبه ومَن والاهم بإحسانٍ إلى يوم الدّين